Örö oúnj÷ Yorùbá

Nõkan Èèlò (Ingredients)

adì÷ - chicken
àgbàdo - corn
àgbæn - coconut
akàn - crab
àlùbôsà - onions
à«áró - yam porridge
ata - pepper
ataare - a type of pepper
àkàrà òyìnbó - bread
edé - shrimp
ëgê - cassava
ëfô - green leafy vegetables
÷ja - fish
÷lêdë - pork/pig
èlùbô - yam flour
ëpà - groundnut
epo - oil (in general)
epo pupa - red (palm) oil
÷ran - meat
÷ran gidi - real meat
èso - fruit
ëwà - beans
ëwà funfun - black-eyed peas
ëwà pupa - brown beans
ewé - leaves
ewédu - a type of green leafy vegetable
÷yin - eggs
gàárí - cassava flour
ilá - okra
«inkafa - rice (note- borrowed from Hausa)
ìrú - fermented locust beans used for seasoning stew
i«u -yams
iyö - salt
máñgòrò - mango
wàrà - milk
æbë adì÷ - chicken stew
æbë ëfô - green vegetable stew
æbë ÷ja - fish stew
æbë ÷lêdë - pork stew
æbë ÷ran - meat stew
æbë ewédu - ewedu stew
æbë ilá - okra stew
æbë tòlótòló - turkey stew
obì - kola nut
ögëdë w÷÷r÷ - bananas
ögëdë àgbagbà - plantains
olú - mushroom
orógbó - bitter kola
òròró - vegetable oil
òròró gbígbôná - hot oil
æsàn - orange
oyin - honey
panla - a type of dry fish
÷ja kékeré kan - sardine
ìy÷fun ìrëkê - sugar
tòlótòló - turkey

Ounje Yoruba (Yoruba Food/Meals)

amala - food made from yam flour
apon - a type of food
booli - barbecued plantains
dodo - fried plantain
dundu - fried yam
eba - food made from cassava flour
ebe - yam porridge
eko - food made from corn
eyin dindin - fried eggs
fufu - food made from cassava
ikokore - food made from water yam
iresi joloofu - jollof rice
iyan - pounded yam
konbiifu - corned beef
moinmoin - food made with black-eyed peas
ogi - hot cereal made from corn
tuwo - food made from corn flour

Ohun mimu (Drinks)

agbo - herbal tea
burukutu - a drink made from millet
fanta - fanta (orange drink)
emu - palm wine
kofi - coffee
kooki - Coke
ogogoro - alcoholic palm wine
omi - water
(omi) osan - orange juice
(omi) gireepu - grape juice
oti - any alcoholic beverage, e.g., beer
oti waini - wine
pepusi - Pepsi
tii - tea

Food Preparation

ba ___ mu to fit ___
bo - to cover
bo eepo - to remove the skin/to peel
din - to fry
fi ___ bu ___ sinu to dish ___ into
fi ___ sinu - to put ___ into
ge ___si wewe - to cut something in small pieces
gun iyan - to pound yam
ho - to boil
ko ___kuro - to remove something
lo ewa - to grind the beans
po - to wrap
re ewa - to soak beans
ro amala - to prepare amala
ro eba - to prepare eba
so ___ sinu to throw something into
to ___ wo - to taste
won iyo - to sprinkle salt
yan - to barbecue

Ohun Eelo (Utensils)

abo - unbreakable bowl
agbon - basket
agolo - can
awo - a plate
fooki
ife - cup
igo - a bottle
ikoko - pot
obe - knife
ori ina - stove top
sibi - spoon
sitoofu - stove

Meal Times

ounje aaro - breakfast
ounje ale - supper
ounje osan - lunch

Miscellaneous

alase - a cook
dun - to be tasty
eepo - skin (of fruit)
ile idana - kitchen
ile-ounje dining room/restaurant
je ounje osan - to have lunch
jeun - to eat
mu - to drink
se - to cook
se ounje - to cook food
soro - to be difficult
obe - soup
oja - market
ori ina - on the fire (for cooking)
ounje - meal
ounje dindin - fried food
ounjekounje - any food
ri mulomulo - looks smooth
tooro - to be smooth
to ___ si enu - to put a drop in the mouth